oríkì fún Òsòósì

2
Oríkì fún Òs òósì Òsoo sì. Awo ò de ìjà pìtìpà. O mo ìyá ògún oníré. Òsoo sì gbà mí o. Òrìs à a dínà má yà. O de tí nje orí e ran. E wà òs òòs ò. Òrìs à tí ngbélé imò , gbe ilé ewé. A bi àwò lóló. Òsoo sì kì nwo igbó, Kí igbo má mì tìtì. O fà ni mó gàfí ìbo n, O ta o fà sí iná, Iná kú pirá. O tá o fà sí Oòrùn, Oòrùn rè . Ogbàgbà tí ngba o mo . Oní màríwò pákó. O de bàbá ò. O dé ojú ogun, O fi o fà kan s os o pa igba ènìyàn. O dé nú igbó, O fi o fà kan s os o pa igba e ranko. A wo e ran pa sí ojúbo ògún lákayé, Má wo mí pa o. má sì fi o fà o wo re dá mi lóró. O ò, O ò, O ò, Òsoo sì ni nbá o de inú igbo jà, Wípé kí ó de igbó re. Òsoo sì oloró tí nbá o ba sé gun, O bá Ajé jà, O gun. Òsoo sì o ! Má bà mi jà o. Ògún ni o bá mi se o.

Upload: paulocarvalho2106

Post on 15-Sep-2015

231 views

Category:

Documents


2 download

DESCRIPTION

Reza

TRANSCRIPT

Ork fn sssoos.Awo de j ptp.Omo y gn onr.soos gb m o.rs a dn m y.Ode t nje or eran.Elw ss.rs t ngbl im,gbe il ew.A bi w ll.soos k nwo igb,K igbo m m tt.Of ni mgf bon,O ta of s in,In k pir.O t of s Orn,Orn r ws.Ogbgb t ngba omo r.On mrw pk.Ode bb .O d oj ogun,O fi of kan soso pa igba nyn.O d n igb,O fi of kan soso pa igba eranko.A wo eran pa s ojbo gn lkay,M wo m pa o.m s fi of owo re d mi lr.Od , Od , Od ,soos ni nb ode in igbo j,Wp k de igb re.soos olor t nb oba sgun,O b Aj j,O sgun.soos o !M b mi j o.gn ni o b mi se o.B o b nb lti oko.k o k il fn mi w.K o re rr d r.M gbgb mi o,Ode , bb omo k ngbgb omo.