bawo ni mo se le mo nipa awon omiran oofa kini awon oofa ... · pdf fileomo ile-iwe giga ninu...
TRANSCRIPT
Bawo ni mo se le mo nipa awon omiran oofa
eto?
Lo si ayelujara ile-ise awon oofa eto
(www.bcps.org/ offices/omp) lati ri
awọn apejuwe eto, awon iwe-ise ati
awọn imo-eri.
Omo ile-iwe ati awọn ebi won tun le
lo si awon apewo oofa ododun ati
eto oofa lati ko eko nipa eto ti won
se ni ile-iwe onikalukuluku. Imo-eri
tun wa ti e ba baa won akeko ile-
iwe soro abi ki e pe offiisi oofa ni
443-809-4127
APERE GBOLOHUN : Awon igbimo ti eto eko ti Baltimore County ko ni shei ase mase lori ojo-
ori, awo, aigbadun, eya, orile-ede ati eya abinibi, iran, esin, isa-aye ibalopo, ologun tabi eyikeyi
miiran ti o wa ninu iwe eto eko,awon ise ti won pese fun ninu ofin ipinle yi.
Kini awon oofa ilana-Ipade?
Awon BCPS oofa eto ni koko-oro curricula ati eto ipase ti ko
wa ni nu okeere ile-iwe eto kan-kan. Won mu omo ile iwe
eko ri ipase aseyori eko, ile eko to ya to, eto eko agbegbe
,ati eto eko lamoja. Awon eto oofa yi mu omo ile-eko lati ile-
iwe deede koja aala ati ti wa ni wole ni pase a si aarin elo
ati Agbani si ile-eko ilana.
Ni pelu awon ebun iyi lati ja de Ile-iwe keji ati wo ile-iwe
giga, awon omo ile-iwe keji ni nu oofa eto yi wa ni anfani lati
dagbasoke ni nu awon nkan ti won ni ife si ati talenti
jakejado specialized iwe ile-ise ati ijinle iriri.
Awon ile-iwe igboro ilu Baltimore County ni eto oofa Ogoji ni
ile-iwe arundinlogun kaakiri County. Awon oota yi ni eto
alagbede, eto isiro, eto imon-ijinle ati imo sise ati iriran ona
pelu eto ise-ori ati eto nipa imon-iro.
Bi omo re ba ni ife si tabi talenti to jo mo ikan ninu awon
eto oofa ti won ni ni awon ile-iwe igboro Baltimore County.
Lo si www.bcps.org/offices/omp lati mo ni pa awon eto ati
awọn ohun elo ilana.
Ile-ewe Baltimore Country to gba alejo eto oofa ile-ewe giga
Off
ice
of
Ma
gn
et
Pro
gra
ms
Ba
ltim
ore
Co
un
ty P
ub
lic S
ch
oo
ls
10
5 W
. C
he
sa
pe
ak
e A
ve
nu
e
To
wso
n, M
D 2
12
04
Bawo ni mo shei le je ki omo mi wo eto oofa?
Bere ni Osuu Setemba, ibewe eto oofa fun odun ile-iwe to
bo ma wa ni offiisi awon e le eto oofa ati ayelujara won ni
(www.bcps.org/offices/omp). Awon obi le yan okan lati bere
fun ibewe ni ori ayelujara. Ibewe tite na wa ni gbogbo ile-
iwe BCPS arin ati giga ati awon isele eto oofa. Ibewe won
lati mun lo si Offiisi awon Eto Oofa ni ijo to pari to le je ipari
osuu Nofemba.
Ni osuu Januari, omo re you ni lati shei iwon iye lati loyeto
fun awon eto. Awon iwon iye yi le pelu idanwo, ifojukoju,
aroko itan tabi afenuka. Awon eto yi yoo pese ofin fun iwon
iye yi lati ran e lo wo lati mura
omo re fun awon iwon iye. Awon
eto mi le ni ki awon omo ile-iwe
shei idawole tabi nkan
orisirisi ki won to shei iwon
iye. Opolopo awon eto yi ni
Iroyin kaadi pelu ohun imọ to
wa po gbogbo ana ibewe wo
awon eto yi. Fun imo-eri pupo
nipa oofa iwon-iye fun ile-iwe
giga, e lo si offiisi oofa ayelujara
ni (www.bcps.org/offices/omp).
Ni Maasi, wa gbo ni pa bo ya won gba omo re si eto oofa
kan. Omo ile-iwe ti won ba gba si inu awon eto yi, won le fun
ni ijoko ninu eto oofa tabi ki won fi si ori iwe iduro ti o wa ni
aarin alaileto lotiri.
Bawo ni omo shei ma ni anfani to ba wa ninu
eto oofa?
Omo ile-iwe giga ninu awon eto oofa ma se oju-ise ninu
awon eto ara tuntun pa pa ju lo ninu eko ayika.
Pelu gbogbo iriri ile-iwe giga, awon omo ile-iwe yi yo ni aye
lati dagbasoke ati ko ogbon ninu nkan to ba ni ife si.
Awon omo ile-iwe ti won wa
ninu awon eto oofa yi ma
ni olomowe aseyori ati
ayeye ju awon ti won si
ninu eto oofa. Won tun ni
idagbaoke ara orunodun
21st to jo mo iwa, ogbon
lati ro inu jinle ati ore
orisirisi. Pelu awon eko kan
ri wipe awon ile-iwe ti won
gba alejo eto oofa ni ajumose
giga pelu awon obi ati awon ara ilu.
Nitori awon eto oofa to wa ninu awon ile-iwe BCPS ni asepo
pelu ara ilu ati awon ile-ise to be ni ilu, awon omo ile-iwe ni
anfani lati ku ro ni ile-eko giga pelu ara ati ogbon orisirisi,
iwe eri tabi iwe ise, iriri ise ati iyi ile-eko giga.
* Bi alayee soki ti awon igbimo Pataki ti eto eko so gbobgo yan pelu eda,
eya, eto-oro, irin-eran ati awon oni aigbadun.
Shei eyikeyi akeko le bere fun?
Eto oofa pese orisirisi eto-eko fun gbogbo awon omo ile-iwe
Baltimore County. Gbogbo omo ile-iwe to lo si awon ile-iwe
igboro Baltimore County le bere fun awon eto oofa to jo mo
nkan ti wan ni ife si tabi talenti won. Awon eto yi le ni awon
idiwo kan, opolopo eto wa fun awon omo ile-iwe ti won wa
ni ite esan (9). Opolopo eto tun wa fun awon omo ile-iwe to
lo si awon ite oke.
Ti omo mi ba ni aigbadun ko?
Awon omo ile-iwe ti won ni aigbadun ni ona lati se eto-eko
to ya to, apa 504 ati awon eto toju ojise ni owo ESOL ni
gbogbo eto oofa. Lati ran awon ebi lo wo bo ya oofa eto kan
bara mu fun omo re, tabi ki ni omo ma ba abi se ni nu awon
eto oofa yi, ba alakoso eto oofa ati ojogbon omo re soro
nipa awon nkan agbara ati eko ti omo re koseemani.
Bi omo re ba gba ibugbe idanwo ni ara akosile eto eko re,
wan pese awon ibugbe yi ko je ara eto oofa iwon iye. Fun
awo abewe ti won wa ni abi ti won lo si ile-iwe igboro ni ilu
Baltimore County, offiisi eto oofa yo baa won abewe yi lati
gba awon eto eko. Awon abewe ti won o lo si ile-iwe igboro
ni ilu Baltimore County lati mu iwe ibugbe idanwo wa pelu
ibewe eto oofa.
Shei igbekoja wa? O ye ki e wo bo ya Adugbo ibi ati igbekoya wa ki e to bere
fun awon eto oofa. Kaluku eto oofa ni ile-iwe giga ni adugbo
ti won ni igbekoja to da ati Ile-iwe igboro ni Baltimore county
ma pese igbekoya lati lo ati bo ni eto oofa ni awon ile-iwe
giga fun awon omo ile-iwe ti won gbe ni laarin awon adugbo
ti igbekoja wa.
Won pese igbekoya lati awon iwonkan ni adugbo* to su mo
awon ile-iwe giga kan. Awon obi ni o wa di di pese igbekoya
fun awon omo ile-iwe lati lo ati bo adugbo ti Igbekoya ma du
ro si.
(Jowo lo si www.bcps.org/offices/omp fun imo-eri pupo.)
*awon iwonkan ni adugbo yi ko bo si abe ofin ti o wa fun ibi ti awon oko
akero ma duro si, ni pa to ibi ti o jinna si ati irin na. Pelu re, ko si
alabojuto kan kan lati awon ile-iwe ni awon iwonkan ni adugbo won yi.
Ti ba ni ibere pupo nko?
Ti e ba fe imo-eri si, jo lo si ayelujara offiisi awon oofa eto
(www.bcps.org/ offices/omp) tabi ko pe ago wa ni (443)
809-4127.
Offiisi awon Eto Oofa
Baltimore County Public Schools
Jefferson Building
105 W. Chesapeake Avenue
Towson, MD 21204 Wo bi fun
imo-eri pupo
Scan Here for